Amoo, Adebisi et al Ede Yoruba Alakoobere Iwe Kefa - West African Book Publishers Limited 1996 - 46 Ede Yoruba Alakoobere je iwe ti a ko ni ibamu pelu korikuloomu tuntun ti ijoba apapo fowo si fun lilo ni ile iwe Alakoobere ni orile ede Naijiria ni odun 1985. ISBN: 978-153-038-3 Subjects--Topical Terms: Education- Language, Yoruba Language